Ajo to n gbogun ti ati idena arun lorileede Naijiria (NCDC) royin lojo ketalelogun osu keje odun yii wi pe, iyen 1,506 ti won fura si pe arun diphtheria ti waye ni ijoba ibile 59 ni ipinle mokanla kaakiri orileede yii.Kano (1,055 igba), Yobe (232),...
Ka siwaju